Deuteronomy 18:1

Ọrẹ fún àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Lefi

1 aÀwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Lefi, àní gbogbo ẹ̀yà Lefi, wọn kì yóò ní ìpín tàbí ogún láàrín Israẹli, wọn yóò máa jẹ nínú ọrẹ ẹbọ tí a fi iná ṣe sí Olúwa, nítorí òun ni ogún un tiwọn.
Copyright information for YorBMYO